Congress MusicFactory
A Gbéeyín Ga
A GBÉEYÍN GA

[ẹsẹ]
Oluwa oun gbogbo
Alagbara
Oba awon oba
Ko s'eni bi re

Aseyi o’un
Olododo
Oluwa mimo
Ko s'eni bi re

[Pre-akorin 1]
A gbe oruko yin ga
Eyin ni iyin at'ogo ye
Ni isokan
Agb’owo soke

[Akorin 1]
Gbe yin ga
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
Af'ogo fun yin

Gbe yin ga
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
A ngbe lati yin yin

[ẹsẹ]
Oluwa oun gbogbo
Alagbara
Oba awon oba
Ko s'eni bi re

Aseyi o'un
Olododo
Oluwa mimo
Ko s'eni bi re

[Pre-akorin 2]
Olorun olotito
Ti wa pelu wa ni irin ajo yi
Ni isokan
Agb'oun soke

[Akorin 2]
Gbe yin ga
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
Af'ogo fun yin

Gbe yin ga
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
Titi aiye

[Akorin 3]
A Gbe yin ga
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
Af'ogo fun yin

Gbe yin ga
A gbe oruko yin ga
Oluwa a yin o logo
A ngbe lati yin yin
A ngbe lati yin yin