Congress MusicFactory
Sí O
SÍ O
[ẹsẹ]
A gboju s’oke (okurin)
A gbowo s’oke (obirin)
A gbo’un soke ni iyin yin (ifohun sokan)
Ife wa fun o (okunrin)
Sii o (obirin)
Okun wa fun o (okunrin)
Sii o (obirin)
A f’aye wa fun ijosin yin (ifohun sokan)
[Akorin]
Sii o (obirin) [Sii o (okunrin)]
Sii o (obirin) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa
Sii O
Sii o (obirin) [Sii o (okunrin)]
Sii o (obirin) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa
Sii O
[ẹsẹ]
A gboju s’oke (okurin)
A gbowo s’oke (obirin)
A gbo’un soke ni iyin yin (ifohun sokan)
Ife wa fun o (okunrin)
Sii o (obirin)
Okun wa fun o (okunrin)
Sii o (obirin)
A f’aye wa fun ijosin yin (ifohun sokan)
[Akorin]
Sii o (obirin) [Sii o (okunrin)]
Sii o (obirin) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa
Sii O
Sii o (obirin) [Sii o (okunrin)]
Sii o (obirin) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa
Sii O
[àdúrà]
Mo fi bùkún fún yín alágbára gíga, mo gbe owó mi sókè sí ìbíi tí ogó yín, mosì fogó fúun yín. Mo wá tókàn tókàn si iwájú yín, mo bòwò fún orúko mímó yín, mo yayé mi sí mímó fúun yín, mo si fi ayé mí se irúbo mímó tíó lè je ìtewó gbà niwájú íte yín. Láti inú okàn mi, mo mú irúbo opé mi wá. Mo fògo fúun yín, mo gbéeyín ga, mo fi ìbùkún fúun yín, mo sì mú ìyin ati ore mi wa fúun yín
[Akorin]
Sii o (obirin) [Sii o (okunrin)]
Sii o (obirin) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa
Sii O
Sii o (obirin) [Sii o (okunrin)]
Sii o (obirin) [Iwo nikan (okunrin)]
A fi isin wa (ifohun sokan)
Gbogbo iyin wa
Sii O
[ipari]
A fi isin wa
Gbogbo iyin wa
Sii O
A fi isin wa
Gbogbo iyin wa
Sii O