Congress MusicFactory
Èyin Nìkan
ÈYIN NÌKAN
[ẹsẹ]
Pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
Ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
Olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
Mo fi iyin fun eyin nikan
[ẹsẹ]
Pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
Ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
Olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
Mo fi iyin fun eyin nikan
[Akorin]
F’eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
Eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
[ẹsẹ]
Pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
Ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
Olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
Mo fi iyin fun eyin nikan
[Akorin]
F’eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
Eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
[Akorin]
F’eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
Eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
[ipari]
Mo fi iyin fun eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan