Congress MusicFactory
Se Orúko Re Logo
SE ORÚKO RE LOGO
[Akorin 1]
Oluwa af’ogo fun oruko re
Oluwa af’ogo fun oruko re
A fun yin logo ati owo
A juba a yin yin
A f’ogo fun oruko re
[Akorin 2]
Nisokan a yi itere ka
A gbe yin s’oke a tun gbe yin ga
Alagbara ati oba
E joba titilai
A f’ogo fun oruko re
[Akorin 1]
Oluwa af’ogo fun oruko re
Oluwa af’ogo fun oruko re
A fun yin logo ati owo
A juba a yin yin
A f’ogo fun oruko re
[Akorin 2]
Nisokan a yi itere ka
A gbe yin s’oke a tun gbe yin ga
Alagbara ati oba
E joba titilai
A f’ogo fun oruko re
[ipari]
Alagbara ati oba
E joba titilai
A f’ogo fun oruko re