Congress MusicFactory
Mímó Ni Òdó Àgùtan
MÍMÓ NI ÒDÓ ÀGÙTAN
[Akorin}
Mimo, mimo
Mimo l’odo agutan
Oluwa alagbara
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o tun nbo wa
[Akorin]
Mimo, mimo
Mimo l’odo agutan
Oluwa alagbara
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o tun nbo wa
[ẹsẹ 1]
Gbogbo eda f’ogo fun o
Gbogbo okan wa bukun f’oruko re
Ede, eya ati awon orile ede
Eniyan mimo nkorin iyin re
[Akorin]
Mimo, mimo
Mimo l’odo agutan
Oluwa alagbara
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o tun nbo wa
[ẹsẹ 2]
A teriba nibi mimo re
A gbowo s’oke a juba re
Oluwa eyin nikan l’owo yi ye
Iwo nikan ni gbogbo iyin ye
Gbogbo iyin
[Akorin]
Mimo, mimo
Mimo l’odo agutan
Oluwa alagbara
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o tun nbo wa
[ipari]
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa t’o nbe
Ti o si wa to tun nbo waaaa