Congress MusicFactory
Wo Olúwa
WO OLÚWA
[ẹsẹ 1]
(Okunrin)
Wo Oluwa lori ite re
Oba awon oba ati Oluwa awon oluwa
Ijoba re wa titi lailai
Agbara ati ola nla re duro titi
(Gbogbo wa)
Wo o joba titi lailai
Eni ologo t’awa feran
Lati ainipekun ko yi pada
Ti o ti wa ti o nbe to si nbo wa
[Akorin}
A gbe yin ga
Ko s’eni t’ale fi o we
A gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
Wo owo re
Apapo eniyan mimo
A fi fun yin ni iyin giga
[ẹsẹ 2]
Wo odo aguntan, omo Olorun
Oba to nsegun oba oun gbogbo
Dun ipe re da araye lejo
J’ekamo pe Oluwa alagbara njoba
[Akorin}
A gbe yin ga
Ko s’eni t’ale fi o we
A gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
Wo owo re
Apapo eniyan mimo
A fi fun yin ni iyin giga
[Akorin}
A gbe yin ga
Ko s’eni t’ale fi o we
A gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
Wo owo re
Apapo eniyan mimo
A fi fun yin ni iyin giga
A fi fun yin ni iyin giga