Congress MusicFactory
Olórun wà níhîn (Halleluya)
OLÓRUN WÁ NIHÍN (HALLELUYA)
[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin
[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin
[ẹsẹ 1]
E wa laarin eniyan yin
Ogo Re si nbuyo
Fihan kakiri agbaye
Ninu olanla Re joba
[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin
[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin
[ẹsẹ 2]
Pawa mo ka di mimo
Mu wa rin gbogbo ona
Dari wa s’ayeraye
Titi lailai ao ma wi
[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin
[Akorin ipari]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun
Oluwa Olorun
Oluwa Olorun wa nihin