Congress MusicFactory
Àmín! (Yorùbá)
ÀMÍN!

[Akorin}
Amin! Be ni yio ri!
Amin! Gbo ase wa!
Ki jobaa re de
Oluwa jeki ife re di sise
Ni sisiyin ati lailai
Amin!

[Akorin}
Amin! Be ni yio ri!
Amin! Gbo ase wa!
Ki jobaa re de
Oluwa jeki ife re di sise
Ni sisiyin ati lailai
Amin!

[ ẹsẹ 1]
Iwo l’Olorun gbogbo eda
Oun’gbogbo wa labe ase re
Mu’dajo re wa s’orile ede
Jeki awon olododo duro

[Akorin}
Amin! Be ni yio ri!
Amin! Gbo ase wa!
Ki jobaa re de
Oluwa jeki ife re di sise
Ni sisiyin ati lailai
Amin!

[Akorin}
Amin! Be ni yio ri!
Amin! Gbo ase wa!
Ki jobaa re de
Oluwa jeki ife re di sise
Ni sisiyin ati lailai
Amin!

[ẹsẹ 2]
Ran oro re si gbogbo aye
J’eka awon ayanfe gbo ipe re
Se wani okan awon eniyan mimo
K’aye leri gbogbo ogo re

[Akorin}
Amin! Be ni yio ri!
Amin! Gbo ase wa!
Ki jobaa re de
Oluwa jeki ife re di sise
Ni sisiyin ati lailai
Amin!

[Akorin}
Amin! Be ni yio ri!
Amin! Gbo ase wa!
Ki jobaa re de
Oluwa jeki ife re di sise
Ni sisiyin ati lailai
Amin!

[ipari]
Ki jobaa re de
Oluwa jeki ife re di sise
Ni sisiyin ati lailai
AMIN!