Congress MusicFactory
Gba ìyin wa [Adúrà]
GBA ÌYIN WA [ADÚRÀ]

Mo fi opé mi fúun yín. Jésù modúpé lówo yín. Olúwami modúpé. Olùdarí mi modúpé. Olúsèdá mi modúpé. Olórunmi, olúrápadáa mi, modúpé. Mojúbà yin. Mo gbé yín ga. Mo gbé yin gégè. Mo sì gbé yín ga. Eyín nìkan lóye láti gba ìyìn mi, mofi ibùkún fúun yín. Eyín nìkan lóye láti gba ìyìn mi, modúpé lówóò yín. Esé o, esé olúwa