Rexxie
Ninu Aye
[Intro: GentleDee & Zlatan]
Hello baby, oruko mi ni gentle
To ba bami roll, sho fe ma fetu
Kuro n be
Kapaichumarimarichopaco

[Chorus: Zlatan]
Abo n sun (ninu aye)
Won ma gba yawo e (ninu aye)
Won o fenu se (ninu aye)
Owo lo le se (ninu aye)
So ti ji saye (mo ti ji saye)
Oo fe ra benz (ninu aye)
Yankee ti ji tipe (ninu aye)
Kilode to wan sun (ninu aye)
Abi o gbeni wa ni (ninu aye)
Kuro n be
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
So ti ji saye (mo ti ji saye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
So ti ji saye (mo ti ji saye)
Kuro n be
[Verse 1: GentleDee]
Lamba to lamba (lamba)
From here down to Ghana (Ghana)
Ijo la ni ko jo ma lo laga (laga)
Malo moti yo ko ma lo stagger (stagger)
Ninu aye won ma fo taba gbori wole
Ahhh.e tan na wole, Hennessy pelu champagne
Ninu aye won ma fo taba gbori wole
Ahhh.e tan na wole, Hennessy pelu champagne

[Chorus: Zlatan]
Abo n sun (ninu aye)
Won ma gba yawo e (ninu aye)
Won o fenu se (ninu aye)
Owo lo le se (ninu aye)
Oo fe ra benz (ninu aye)
Yankee ti ji tipe (ninu aye)
Kilode to wan sun (ninu aye)
Abi o gbeni wa ni (ninu aye)
Kuro n be
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
So ti ji saye (mo ti ji saye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
So ti ji saye (mo ti ji saye)
Kuro n be
[Verse 2: GentleDee]
Ji malo sun
Omo yahoo yahoo
When I enter the hood
Dem say na who na who
Sashe ko gba naira ko gba dollar ko lo se lowo aboki
Won ni lamba ti mon fun won ni street ti poju, kin se lo ni soki
Sister linda
You fit like mirinda
Follow me go my villa
Ka lo jo walicilusha

[Chorus: Zlatan]
Abo n sun (ninu aye)
Won ma gba yawo e (ninu aye)
Won o fenu se (ninu aye)
Owo lo le se (ninu aye)
Oo fe ra benz (ninu aye)
Yankee ti ji tipe (ninu aye)
Kilode to wan sun (ninu aye)
Abi o gbeni wa ni (ninu aye)
Kuro n be
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (mo ti ji saye)
So ti ji saye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (ninu aye)
Ninu aye (mo ti ji saye)
So ti ji saye (ninu aye)
Kuro n be