IFe Ogunwumiju
Ewure
Oni ka lu ku
Jeje eru re
Eru re

Onikalu ku
Jeje agun tan
Agun tan

Oluronbi jeje omo re
Omo re
A pon bi epo

Oluronbi o
Jo jo
Iroko Jo jo

Oni ka lu ku
Jeje eru re
Eru re

Onikalu ku
Jeje agun tan
Agun tan

Oluronbi jeje omo re
Omo re
A pon bi epo
Oluronbi o
Jo jo
Iroko Jo jo

Jolojolo
Jojo iroko Jojo
Jolojolo
Jojo iroko Jojo
Jolojolo
Jojo iroko Jojo
Jolojolo
Jojo iroko Jojo

Alu jan jan ki jan
Iya iya de kun de le
Alu jan jan ki jan
Gbo ara ye pa yeye re je
Alu jan jan ki jan
Ijapa gbe ti e o do run
Alu jan jan ki jan

Iya iya de kun de le
Alu jan jan ki jan
Gbo ara ye pa yeye re je
Alu jan jan ki jan
Ijapa gbe ti e o do run
Alu jan jan ki jan
Alu jan jan ki jan
Alu jan jan ki jan
Alu jan jan ki jan
Alu jan jan ki jan

Ah ah
Eh
Eru oba ni moba oba to
Eru oba ni moba oba to

Oba to
Eh
Eh

Hmm hmm hmm

Babalawo mo wa bebe
Alugbinrin
Babalawo mo wa bebe
Alugbinrin
Oni n mama mowo be nu
Alugbinrin
Oni n mama fese be nu
Alugbinrin
Mo bo ju wo le
Momu be nu
Alugbinrin
Babalawo mo wa bebe
Alugbinrin
Babalawo mo wa bebe
Alugbinrin
Babalawo mo wa bebe
Alugbinrin
Uh uh uh uh
Alugbinrin
Eh eh eh eh
Alugbinrin
Alugbinrin
Alugbinrin

Ye e ye ye ye
Alugbinrin
Ah ah ah ah
Alugbinrin
Alugbinrin

Ah ah
Alugbinrin

Hmmm hmmm hmmmm
Hmmmm