Everyday, so God...
Bacause of you. I dey live, I dey breath, I dey eat
So, I wanna have some talk with you
Ọrun ṣ'ilẹkun, I wanna have some talk with you
[Verse 1]
Nítorí rẹ mọ ṣe l'ọlá
Nítorí rẹ mọ ṣe ń ṣ'oge
Nítorí rẹ mọ ṣe ń ra moto
Mo wọle, mọ b'Olúwa mi s'ọrọ
Nítorí rẹ mọ ṣe wá l'ayé
Nítorí rẹ mọ ṣe wo aṣọ s'àrà
Nítorí rẹ mọ jí l'òwúrò
Mo wo ayé mi n'ọdẹ ye, ya
A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Nítorí rẹ mọ ṣe ń gbó ìròyìn ayọ, lai s'owó, lai sì nkan kan
Ìyà òní l'ayo ọla o, b'Olúwa ti wi bẹ náà lórí
Jiji moji lowuro
Moji si inu ipese re
Ayo at'alafia ye ye
O, o o oni pe ki n ma se beru
A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Melo la fe so
Melo lo si n bowa
Melo la fe so, eh
Melo lo si n bowa
Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh
Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh
Ninu iponju, Ninu idamu
B'ebi ba n p'ona
Mawole, maboluwa mi soro
B'emi o le yan
Baye ba foju dimi
B'emi o le ni
Mawole, maboluwa mi soro
A o, Aa a o o ibafeledu'a
A o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Nínú ìpọ́njú, nínú ìdààmú
B'ẹbi ba ń p'ona, má wó ile ma b'Olúwa mi s'ọrọ
M'oní f'ojú sunkún mo
Aye loja, oh oh... Orun... Orunile
And that's fine by me... Eh eh...
Oh... Ye ye... Bring it down... Oh oh...