Olorun to da awon oke igbaani
Eyin ni mo fi ope mi fun
Olorun to da awon oke igbaani
Eyin ni mo fi ope mi fun
Tani ngo tun gbe ga o, bi ko se Baba l'oke
Tani ngo tun fi gbogbo ope mi fun

Eyin ni mo fi okpe mi fun
Olorun to da awon oke igbaani