Oni warapa ti rolu magun, khasa
Kokanmi, kokanmi
Qdot l'oruko mi (kokanmi, kokanmi)
Mo mo pe mo mi le shey n f'obo lomi
Mio l'ori lo gun pe ibon o le ran mi
Bibeli mo ni pelu Qurani
Pelu kini baami to dun woro-woro
Eni f'oju di ina, ina a jo
Iya Ibadan oya gb'agbo le ina
Epo ogede ko le yo mi
Maape bi Alaafin Oyo ni
Werey ni won mo ma le won s'Aro
Ma gbe won lo bi dodo Iya Alaro
E fun mi ni hammer, kin foh won lori ka
Awon werey, awon motherfucker
E ro dada k'eto b'eshu lowe
E soh fun shigidi, ko ma r'odo lo we
Kilonje ko s'ewe ko s'egbo ninu aye?
K'Olohun maje a rija aiye ni
Shi-o kelebe (kokanmi)
Won ni pe Picker die (kokanmi)
Pe client o s'oro mo (kokanmi)
Pe iyawo yin nshеy olosho (kokanmi)
O sun yara Landlord (kokanmi)
Won fe mo'di abajo (kokanmi)
Tani baba alajo? (Kokanmi)
E re ile Babalawo (kokanmi)
Ebo yin ma foh m'awo (kokanmi)
Woni pе Yahoo ni (kokanmi)
Woni pe a sh'ogun owo (kokanmi)
Oni warapa rolu magun (kokanmi)
Pe Lagbaja bo'ju k'orin (kokanmi)
Eni oyinbo o dun lenu mi (kokanmi)
But local mi n ja'wo (kokanmi)
Oke Kilimanjaro sope Olumo o ga
Agbo t'aja, agbo t'eran
Ewo ni t'agutan lori aga?
Won ni mo local, mo n pa'wo lo
Omo Folashade, mo ti gb'ade lo
Oyingbo le ma dun lenu mi
Eyi tinba soh, Wole Soyinka l'aba yin tu
E wa wo eleko to yan odi s'oni moi-moi
Oni bugan binu elewa agoyin
I don't care if you like or not
Eni shishee lo ma pa'wo
Kokoro to njo leba ona ni, onilu re nbe ninu igbo
Mo ti goke mo ti shee lo k'afara to ja
Mo jaapa, k'oyinbo to ja
Omode ana ti wa d'agba
Qdot, omo imale afeleja
E ro dada k'eto b'eshu lowe
E soh fun shigidi ko ma r'odo lo we
Kilonje ko s'ewe ko s'egbo ninu aye?
K'Olohun maje a rija aye ni
Shi-o kelebe (kokanmi)
Won ni pe Picker die (kokanmi)
Pe client o s'oro mo (kokanmi)
Pe iyawo yin nshey olosho (kokanmi)
O sun yara Landlord (kokanmi)
Won fe mo'di abajo (kokanmi)
Tani baba alajo? (Kokanmi)
E re ile Babalawo (kokanmi)
Ebo yin ma foh m'awo (kokanmi)
Woni pe Yahoo ni (kokanmi)
Woni pe a sh'ogun owo (kokanmi)
Oni warapa rolu magun (kokanmi)
Pe Lagbaja bo'ju k'orin (kokanmi)
Eni oyinbo o dun lenu mi (kokanmi)
But local mi n ja'wo (kokanmi)
Jirafa jalika ra fali eli malaika mi Orimolade
Eni f'oju di ina, ina a jo
Iya Ibadan, oya gb'agbo le ina
Epo ogede ko le yo mi
Maape bi Alaafin Oyo ni
K Sir Sosse
King of Marley
Musa Felix for Garuba
Femi Jaguar nilu London
Mo mo Baddy Oosha
Lanre Typical
Milli omo Salawe
Mo mo Femi Chill Music
Mo mo Billique mo (mo Bili)
Mo mo Doctor Brown
Mo mo Arowolo
Arowolo tin ta motor
Mo mo Bottles
IBD Dende
Alashe Nikas Teni Level
Moti mo Water
Mo mo Owo Mabo
Bunmi simple casher
Mo mo Unique Motors
Mo mo Climax
Mo mo Pasuma Wonder, omo iyawo Anobi l'Omole
Xsmile
(Yeah, who's here?)
Quick as sure boys