Lagbaja
Olagbaja Ma Tun De O
O de o
Olagbaja ma tun de o
O bo sokoto k’ enu e da’le
Olagbaja ma tun de o
Chant: Olagbaja nbe lode
Eru o le ba wa o
Olagbaja nbe lode
Eru o le ba wa o
Chant: Ko i ye won
Yio ye won lola
Chant: Olagbaja ma tun de o
O bo sokoto k’enu e da’le
Olagbaja ma tun de o
Chant: Wa fun wa ni’lu
Ilu orin
Wa fun wa ni’lu
Ilu orin