Lagbaja
Faa-To
Omo te nwo yi, Ko ma se ipanle
Kii se pa mi nku sori benbe soko
Mo ko loro o
Ewo, ewo, ewo, ewo ewo pounbele

To…omo temi kii jefoti - Fa …To!
Omo temi kii jepa – Fa…To!
Omo temi kii jegbarun – Fa…To!
Omo temi ije beliti – Fa…To!
To ba mo pe o fe gba boolu
O ba kori si papa
Gboju oke.. ko wo mi loju
En… wo mi loju
Oju loro wa
Gbogbo wa mo lo fe
Tebitebi lo faya
Woo… ebi nle repete
O ye abi o ye?
O ye abi o ye?

So moriki re- Jenke
So moriki re –Jenke
To ba ti mo poo le ke o
Fododo mi le jeje o
Feyinju mi le jeje o
FAjike mi le jeje o
FAmope mi le jeje o
FAmoke mi le jeje o
Fi Jenke mi le jeje jeje jeje

E dakun e moo da mi lohun
Baa se nkira wa ni city wa
En Odogun Agbegba join together
On gangan niyen
E moo pe… Oo…In
O ya - Oo…In
Oluwa to fi yi sike ara yin - Oo
A ba yin kale dojo ale - In
E o ni ku ni kekere - Oo
Ee lo ra yin gbo dandan - In
Ninu ola, ola on alaafia
Ayo yin a wa kale
Ee ni kabamo
Ee bako, ee babo
Ee kole mole, Ee rale mole
Asiri yin o ni tu o laraye lowo
Iko kan ii kejo lona
E mo lo re, e mo boore
Iko kan imo i kejo lona
E mo lo re, e mo boore
Sese lomode nyo meye
Se se se se se se se se…
Sese lomode nyo meye
Gbogbo aye o ma yo moo yin
Ise yin o ni dise moo yin lowo
Ise yin o ni baraye ninu
Edumare to mu yin pade ara yin
Yio mu yin se alabapade ire
Yio moo duro ti yin gboin gboin
Gboin gboin gboin gboin…