Adekunle Gold
Fight For You
[Verse 1]
Hello Sweety! Don’t cry; don’t cry;
Wipe your tears
Awelewa, ma a worry; I go take you go O
Pretty baby; don’t cry; big girls no dey cry [no dey cry]
Awelewa, ma a worry; you go follow me go
Bobo to fe e s’ile, se b’o se n se e ni yi o?
Eni l’ori o ni fila; se b’o se n t’oju e ni yi o?

[Chorus]
Make I Fight For You; now, now, now;
Ololufe o [Je n jaa fun e o]
Ayaba ki n sun ‘kun [ahhh];
Ayaba ki n j’iya a [ahhhhh] (Je n jaa fun e o)
You supposed dey happy [ahhh];
You supposed dey laugh o [ahhhhh] (Je n jaa fun e o)
Je n jaa fun e o [ahhh]; jaa fun e;
Oh baby o [ahhhhh] (Je n jaa fun e o)

[Verse 2]
T’oba je Mike Tyson ni, mo ni size e l’owo
T’owo mi o ba ka, mo ni Bajinotu n’ile o
Bobo to fe e s’ile, se b’o se n se e ni yi o?
Eni l’ori o ni fila; se b’o se n t’oju e ni yi o?

[Chorus]
Oleremi; make I Fight For You; now, now, now;
Ololufe o [Je n jaa fun e o]
Ayaba ki n sun ‘kun [ahhh];
Ayaba ki n j’iya a [ahhhhh] (Je n jaa fun e o)
You supposed dey happy [ahhh];
You supposed dey laugh o [ahhhhh]
[Je n jaa fun e o]
Je n jaa fun e o [ahhh]; jaa fun e;
Oh baby o [ahhhhh] (Je n jaa fun e o)
(Verse 3)
Ahh; ahhhh; ahhh; ahhhhh;
Ah, ah, ah, ah, ah, ahh
Make I Fight For You o;
O le f’eyin ti, f’eyin ti mi o
Awelewa; s’o gbo? (s’o gbo? s’o gbo? s’o gbo?)

[Outro]
Yeh; ohh; yeh, ehh; ohh
Make I Fight For Youuu (oh, oh, ohhhhhhhhh)
Je n jaa fun e o (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
Awelewa (Ayaba, Ayabaa)
[Oh, oh, ohhhhhhhhh]
[Je n jaa fun e o] [Oh, oh, ohhhhhhhhh]
Make I; Make I Fight For You
Nah, nah, nah, nah; nahh [oh, ohhhh]
Je n jaa fun e o] (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
You supposed dey happy o; eh, eh, ehh
(Oohhhhhhhhh)
Ayaba, Ayabaa
Je n jaa fun e o (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
Awelewa, ahh; ahh; s’o gbo o? [Oohhhhhhhhh]
Je n jaa fun e o (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
Oh, oh, oh, oh, ohhh (Ayaba, Ayaba, Ayabaa)
Oh, oh, ohhhhhhhhh
Je n jaa fun e o (Oh, oh, ohhhhhhhhh)