Wo Olúwa

from A Gbéeyín Ga (2019)
WO OLÚWA



[ẹsẹ 1]
(Okunrin)

Wo Oluwa lori ite re

Oba awon oba ati Oluwa awon oluwa

Ijoba re wa titi lailai

Agbara ati ola nla re duro titi



(Gbogbo wa)

Wo o joba titi lailai

Eni ologo t’awa feran

Lati ainipekun ko yi pada

Ti o ti wa ti o nbe to si nbo wa



[Akorin}

A gbe yin ga

Ko s’eni t’ale fi o we

A gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re

Wo owo re

Apapo eniyan mimo

A fi fun yin ni iyin giga



[ẹsẹ 2]

Wo odo aguntan, omo Olorun

Oba to nsegun oba oun gbogbo

Dun ipe re da araye lejo

J’ekamo pe Oluwa alagbara njoba



[Akorin}

A gbe yin ga

Ko s’eni t’ale fi o we

A gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re

Wo owo re

Apapo eniyan mimo

A fi fun yin ni iyin giga



[Akorin}

A gbe yin ga

Ko s’eni t’ale fi o we

A gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re

Wo owo re

Apapo eniyan mimo

A fi fun yin ni iyin giga

A fi fun yin ni iyin giga

More from A Gbéeyín Ga (2019)

More by Congress MusicFactory

All Congress MusicFactory songs →