Brymo
Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn)
Gbemi san le
Ko mi sita
Fami lewu ya
Temi lorun pa
Eniyan lasan ni mo je
Mo fuye bi paper
Iji ja lodo
O gbemi lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Emi ni imole
Olukunkun wo gbo lo
Mo fa lewuya
Mo te lorun pa
Eniyan lasan mi o je
Mo wiwo bi ésan
Emi ni iji toja lodo
To k'ogba won lo soko
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Okunrin meta debi ti mo n lo