Olamide
Anifowose

[Chorus]
Ọmọ Anifowose, ọmọ Anifo—
Irú ki l'eyi? Ọmọ Anifowose
Ọmọ Anifo—
Irú ki l'eyi, ọmọ Anifowose
Wọn m'ewúré dúdú, wọn mu re igbó ifa
Ọmọ Anifowose
Wọn m'àgùntàn bolojo, wọn mu re ilé oṣun
Ọmọ Anifowose
Oṣun o gb'àgùntàn ema ṣe gb'emi mi
Ọmọ Anifowose
Ẹni ti o le ṣe bi alaaru l'Oyingbo
Kò le ṣe bi adegboro l'oja oba
Ayinde o, eh
Ayinde oo

[Verse 1]
Won ni kilode
Ki lo ba de, ki lo n wa n bi, ki lo fe
They never thought I'll make it to the top
But that's not fair
To ri mommy wa o l'owo
To ri daddy wa o l'owo
Hustled from the house and every damn
Thing na sorrow
Mo ya je solo o
A de solo o
Dem be High class dem say we are so low o
Mommy ta'so ati bata e fun paro
Daddy ta'so ati bata e fun paro
To put food on the table
Ko ma d'abi pe won wa capable
Salary daddy o wa stable
Everyday ko la ma je vegetable
Buh mummy know God is able, ice water la ma ti fi mu
Garri lebu
Awon omo Landlord chance wa
Cos won pass wa, won embarass wa
Won ni e kuro ni house wa
Won frustrate mommy ati house wa
Awon omo alhaja
To ba so mi m'ole le yin, ma ja
Mi wa ja but t'owo mi ba d'eyan, wa ja
[Chorus]
Ọmọ Anifowose, ọmọ Anifo—
Irú ki l'eyi? Ọmọ Anifowose
Ọmọ Anifo—
Irú ki l'eyi, ọmọ Anifowose
Wọn m'ewúré dúdú, wọn mu re igbó ifa
Ọmọ Anifowose
Wọn m'àgùntàn bolojo, wọn mu re ile oṣun
Ọmọ Anifowose
Oṣun o gb'àgùntàn ema ṣe gb'emi mi
Ọmọ Anifowose
Ẹni ti o le ṣe bi alaaru l'Oyingbo
Kò le ṣe bi adegboro l'oja oba
Ayinde o, eh
Ayinde oo

[Verse 2]
Mo n da gbe
Mo n da fa
Mi o mo ile onisegun, mi o mo ile alfa
Bo ya mommy ati daddy lo sise lori mi
Glory be to alpha
Before life hard
Poverty fi mi se cypher
Sorrows and pain ma fi mi cat walk
Won Ma tun se high 5
So we roll up just to get high but
Poverty no stop so my guys open eyes
Oga Ade
Ewo ibi ta ba de
Omo eru d'oba
Igboro demilade
Ema kun pancake
Me I am getting my cake
N***as dem be like ee
When they see my picture on the like ee
Them no rich God
Them know this
Won fe si office le mi lori
Se mo jo novice
God I love this
I keep rolling like a borris
Versace, versace
You rocking versace
Your Mommy is suffering, oloshi
Emi ti flourish, awon parents mi jeun to nourish
[Chorus]
Ọmọ Anifowose, ọmọ Anifo—
Irú ki l'eyi? Ọmọ Anifowose
Ọmọ Anifo—
Irú ki l'eyi, ọmọ Anifowose
Wọn m'ewúré dúdú, wọn mu re igbó ifa
Ọmọ Anifowose
Wọn m'àgùntàn bolojo, wọn mu re ile oṣun
Ọmọ Anifowose
Oṣun o gb'àgùntàn ema ṣe gb'emi mi
Ọmọ Anifowose
Ẹni ti o le ṣe bi alaaru l'Oyingbo
Kò le ṣe bi adegboro l'oja oba
Ayinde o, eh
Ayinde oo

[Outro]
Long live king wasiu ayinde marshall
For the inspiration
Living legend toh bad
Kwam I the ultimate
Mo sample your voice baba, e ma kana
Olamide badoo