Banky W
Jasi
[Intro]
(Ma—Ma—Masterkraft on the beat)

[Verse 1: Banky W]
Omoge, jasi, mi o ni Maserati
Mi o le gbe e sinu Bugatti
Ahn, mo ni ko jasi
But wo le kapa e (Kapa e)
Ma kapa e (Ma kapa e)
Ti m ba gba e (Ti m ba gba e)
Ma kapa e (Ma kapa e)
Ma sun toju e (Toju e)
Ma toju e (Ma toju e)
Ti ma gba e (Ti ma gba e)
Ahn, ki lo n se e na
Je n fun e nkan

[Chorus: Niyola & Banky W]
Ki lo fe (Ha)
Ki lo fe
Samba (Samba)
Ki lo n se e na
Je n fun e nkan
Ki lo fe (Ah, heh)
Ki lo fe
Samba (Samba)
Mm, mhm
[Verse 2: Banky W]
So fe faaji
King of the Lagos party
Ehn, mi so fe faaji
King of the Lagos party
Omoge, jasi, mi o ni Maserati
Ki lo kan mi kan Bugatti (Ehn)
Who's your daddy?
Ani mo le kapa e (Kapa e)
Ma kapa e (Ma kapa e)
Ti ma ba gba e (Ti ma gba e)
Ma kapa e (Ma kapa e)
Mo ma toju e (Toju e)
Ma toju e (Ma toju e)
Ti ma gba e (Ti ma gba e, ha)
Ki lo n se e na
Je n fun e nkan

[Chorus: Niyola & Banky W]
Ki lo fe (Baby, wa gba, ha, baby wa gba)
Ki lo fe
Samba (Samba)
Ki lo n se e na
Je n fun e nkan
Ki lo fe (Baby, wa gba, baby, wa gba)
Ki lo fe
Samba (Samba)
Mm, mhm
[Verse 3: Banky W]
Strong ting
Toh mu naa da kan
Stop fronting
Wa gba ko yo
Baby, wa gba ko yo
Ki lo n se na
Je n fun e nkan
O fe tele Mr. W, what's wrong with you?
Ehn, ehn
Ehn, ehn
Oya, tele Mr. W, what's wrong with you?

[Chorus: Niyola & Banky W]
Ki lo fe (Baby, wa gba, ha, baby wa gba)
Ki lo fe
Samba (Samba)
Mm, mhm
Ki lo n se e na
Je n fun e nkan
Ki lo fe (Baby, wa gba, ha, baby, wa gba)
Ki lo fe
Samba (Samba)

[Outro: Banky W]
Kilo—Kilo—Kilo n se, je—je n fun e nkan (Ha, he-he)
Samba (Samba)
Baby, wa gba
Je—Je n fun e nkan
Ehn, ehn? Ehn, ehn?
Samba (Samba)
Baby, wa gba
Samba (Samba)